Decentralized Social
Ajo nẹtiwọki & Isanwo System

TRAVELFLEX

Your last chance to buy TRF coin.
Funds raised during the last 7 days period will go to charity.

LAST CHANCE TO BUY TRF

Iye owo fun owo $ -
Duro ni
00
Ọjọ
:
00
Awọn wakati
:
00
Awọn iṣẹju
:
00
Awọn aaya
0M
|
2.5M
|
5M
|
7.5M
|
10M
|
0%
TRAVELFLEX
Kini ati pe kilode ti o ye ki fi ma lo?
Travelflex je crytocurrency titun ti o gbenro la ti yanju isoro onisepupo ti awon koini miran bi. Bitcoin doju ko lowolowo. Nipa lilo algorithm to da lori DAG titun, Travelflex ki n se idakeji laasan abi aami.
Ere buloki fun apeere je bloku kan ni iseju aya kan, yato si buloki kan ni iseju mewa ti Bitcoin. O ma je proof of work (POW) koini otito ti o ṣe rọ ti o si ṣe lo pelu netiwoki tire yato si aadorun pasen awon koini to ku.

Ma je ki oruko Travelflex si e lokan nitori koini yi se lo fun ohunkohun to je mo eto isanwo, Ki nse fun irin ajo nikan.
Ipo Oja

Visa le mu bi awon isowo 1700 ni gbogbo iseju aya (tps), a pe ni deedee oluwon ojoojumo ti egberun merin. PayPal, ni ifiwera, yanju bi milionu mewa idunadura ni ojumo fun 115 tps ni ipari odun 2014. Ni oni, Bitcoin netiwoki o ko ja 7 tps nitori ilana Bitcoin lati ma je ki buloki ju 1MB lo.

Laipe pelu awon ilosiwaju, e je ki a ni a so iwon bloku di 2MB, ajepe oluwon na a di ilopo meji a si di 14 tps.

Bitcoin – idanadura meta si merin ni iseju aya kan fun 1MB, tps mefa si mejo fun 2MB (cost=2-10 USD) fun 1MB
Ethereum – idanadura ogun ni iseju aya kan (oye=0.01-0.1 USD+)
PayPal – idanadura 193 ni iseju aya kan.
Iota idanadura 500 si 800 ni iseju aya kan.

Travelflex (TRF) – idanadura 1200 si 1400 ni gbogbo iseju aya eleyi yi o sare si pelu olumulo pupo. Iye owo je odo!

Wo fidio yii
Awon amuye pataki Travelflex:
E darapọ mọ wa lori ianisoro telegram!
Ai ki e darapo mow a lori ero ianisoro media awujo:
E fe mo ni pa wa
Ki ni a pe ni Travelflex?
Ile ise irinajo je ikan lara awon ile ise ti o tobbi ju ni agbaye, pelu idagbasoke dada ni ododun. Ni odun 1995 bi eyan milionu 520 eyan ni o lo irinajo ni agbaye. Ni ogun odun si, ni odun 2015, numba yi dagba di Milionu 1,065 eyan. Ile ise irinajo n pese ise fun ju 292 milionu eyan, eyi si je 10.2 pasenti ise ni gbogbo agbaye.
Awon arin irinajo koko fi owo afojuri sanwo, nigba to ya won lo sowedowo arin irinajo, ni ipari a ni kaadi isanwo ti a mu pipe se owo fun irinajo rorun. Pelu idagbasoke awon ona ti o dara ta n fi rin irinajo ati kiikan ti oko ofurufu, di de egbe miiran aye ti di Irorun.
Irinajo ti yipada ninu awon odun ti o ti koja, sugbon a wa ti a wa ni Travelflex ni igbagbo pe a la gbe de ipele ti o tu ga julo. Travelflex fe lati so ile ise-ajo mo blockchain, lati mu ajo Din owo ati ni aabo si.
NI gba ti o ba sanwo pelu koini Travelflex (TRF), o ni lati se aniyan nipa a n san owo ti o po fun pasipaaro owo afojuri, lilo ATM or kaadi kerediti.
TRF re o le sonu or ki won ji, yato si owo afojuri abi kaadi kerediti ti o mu lo si ibi ti o nlo. O ni lailai ni wahala pelu ATM ti o fe gba kaadi debiti or ki o te gbe kaadi re je. Travelflex a wa pelu kaadi afojuri ti re ti a le lo ni gbogbo ATM.
Siwaju si, a fe fi Travelflex ATMs loto si awon ibi irin-ajo pataki, lati le je ki o te TRF jade bi sowedowo arin irin-ajo ati ki o le ye sowedowo ni awon ATMs wa. Koini ti a te yi sise pelu Pin koodu ti re nikan, bi paapaa ti o ba padanu ite jade re, ma se aniyan, enikeni ko le lo sowedowo re.
Won le ji alaye ori kaadi kederiti re pelu irorun. Nigba ti o ba fun wan ni kaadi kerediti re ni ile itura, enikeni le da alaye ori kaadi kerediti re ko pelu irorun and si lo fun ara re ti o ba ya. Pin koodu ti wo nikan ni lati sise.
Nigba ti o ba sanwo ni ile itura, TRF ma sise bi escrow. Awon koini o ni di sisan ti di ojo ti o de, pelu itewogba in-app re. Bi, paapaa ti o ba de ibi tin lo o si dabi wipe ile itura yi ko si ni aye abi won o fun e ni ise ti won se ileri, o ni lati aniyan nipa si so owo re nu.
Ki lo tu wa, a ma se iwakusa TRF lati o ri ohun elo ero igbeka wa. Ko ni si idi fun hardware ti o gbowolori, CPUs, kaadi girafiki or ASICs. Gbogbo eyan ti o ni ero ibanisoro le ro TRF. Ohun elo ero alagbeka je ohun elo awujo ti o yato. O ni oro ore, ise iwiregbe ti o ni idaniloju o si se opo mo social media.
TRF o fe mu iyipada ba bi a nse rin irin-ajo nikan, a bikita nipa mimu ayipada ba gbogbo aye. Nitori eyi ni a se gbe orisirisi apamowo dide fun itore aanu. Igbakigba ti o ba wa TRF, wa ni anfani lati fe di e Ni nu TRF fun ohun to dara.
Fun alaye si lori cryptocurrency, iwakusa, blockchain ati TRF, ye FAQ wa wo.
Ka siwaju
Awon eya ara ohun elo alagbeka
Iwakusa
Enikeni pelu ero ibanisoro ni anfani lati wa koini travelflex (TRF) pelu.
Apamowo
Ohun elo ero alagbeka yi ni apamowo ti a ti semo. Ko si idi fun apamowo lati ita.
Ore Ore
Wa ni anfani lati fi awon olumulo ohun elo ero alagbeka miran so ri ti re. wa ni awon ore, ebi ati awon eyan miran ninu ore ore kan.
Iwiregbe
Wa ni anfani lati ba awon ore, ebi, ati awon olumulo miran sori ise iwiregbe ti o ni idaniloju.
Near field communication
Wa ni anfani lati wa awon olumulo Travelflex miran ni ayika re ki o si beere si n ba won soro.
Social media
O le so ohun elo yi pelu social media. Nigba ti o ba se eyi, lesekese wa gba ajeseku iwakusa.
Iranlowo ni igba gbogbo
A ni egbe ti o wa ni igbaradi lati ran e lowo ni igba gbogbo nipa se ise iwiregbe.
Itore aanu
Ni gba ti o ba wa koini TRF titun, o ni anfani lati fi koini si ipawomo ti o ba wu ho.
ESCROW & price locking
Travelflex o ma toju owo re titi di igba ti o ba gba sisan owo. Yo tun rii daju pe iye ti o Wa lori tita oja ti isiyi nigba ti o ba mu TRF sise fun sisan.

Travelflex ni media

Roadmap
Q4 2016
2016
Aba akoko ni o wa sinu okan oludasile. Idasile.
Q1 2017
2017
Awon ti o nife si cryptocurrency meji darapo mo oludasile won si da egbe sile leyin Erongba Travelflex.
Q2 2017
2017
Egbe akoko ni won kojo fun ise akanle won si se ilana erongba. Awon amoye si beere si se idagbasoke beta ohun elo alagbeka lori Android ati iOS platform. Ise iwerigbe ni a danwo ti asi tun mudojuiwon titi ti o fi sise pelu aseyori.
Q3 2017
2017
Won se ipinu lati fi ipile ile-ise si Hong Kong. Lati le wa laarin ikan ninu oja ti o ni agbara julo ni Asia-Pacific. Awon oro ofin ati awon inowo owo ni a fun ni aabo. Logo Travelflex ati aami-isowo ni a fisile.
Q4 2017
2017
Travelflex gbaradi lati beere Initial Coin Offering. Idanwo ipari beta ti ohun elo alagbeka di asetsan. Egbe ti o wa ni idi iwiregbe igbesaye ti gbaradi lati dahun gbogbo ibeere.
ICO
2017
Iseto agbaye ti Initial Coin Offering Travelflex. Koini 95,000,000 ni o wa fun tita, Koini 5,000,000 yo losi eto amojuto Travelflex. Awon koini ti won o ra o di jijo ni ina pelu eri Jijo ni ina.
Q1 2018
2018
Iwakusa koini TRF beere. Idagbasoke sowedowo ati kaadi afojuri Travelflex wa ni liosiwaju. Travelflex o ma fi TRF si ori awon pasipaaro pataki fun isowo.
Q2 2018
2018
Sowedowo ti o se te jade ma wa. Idasile ajosepo pelu awon olori ninu ise-ajo, lati le je ki agbegbe Travelflex ma lo TRF won ninu awon isowo nipase awon ise fifipamo, awon ile-ise ofurufu ati awon ile itura.
Q3 2018
2018
Kaadi afojuri Travelflex di ti tu sile a si se lo ni ATMs. Awon eto isooto wa ni idagbasoke. Ajosepo pelu ile-ise GDS yoo bere lati le je ki awon olumulo je anfaani awon Ise Travelflex.
Q4 2018
2018
Kaadi afojuri Travelflex ye ki o bere ise bi a ti se ipinnu ati si di gbigba ni ibi ti o posi.
Q1 2019
2019
Travelflex o tesiwaju lati ma se idagbasoke ibasepeo titun pelu awon alabasepo. E leyi ni lati je koini di gbigba si ati ilo pupo fun awon ti o ni. Egbe atileyin si wa si be lati pe se iranlowo.
Q2 2019
2019
Egbe na yo tesiwasju lati sise lori ohun elo alagbeka. Ero titun leti wa ni idagbasoke. Ni akoko yii, ile-ise cryptocurrency le ti di ofin Travelflex si ti pese sile owo ati amofin ti o ba je dandan lati le je ki TRF maa sise lo ninu ofin ti o wa lile. E leyi na wa fun awon ibeere pataki ti a nilo ko to di akoko yii.
EGBE
Peter Hoogslag
CEO
Peteru ti wa ninu oro cryptocurrency gidigan lati ibere re ni odun 2009. O pinnu ninu ogbon lati koju iwakusa Bitcoin ni odun 2011 o si ti ni aseyori pupo lati igbayi. Peteru mo nipa gbogbo abala aye cryptocurrency, lati iwakusa si isowo, di nini cryptocurrency. Pelu imoye nla re o ti pero lati se agbekale koini tire. TRAVELFLEX.
Bing Hayashi
Olori Onimo-Ero
Bing ni olori onimo-ero wa. Leyin igba to gba PhD re ninu imo ero, o ti sise gege bi back-end software developer o si bere si sise lori imo ero blockchain ati smart contracts ni akoko faaji. O ti je onimo-ero komputa fun PTT, Gas & Oil line operations.
Marcel Hoogslag
Igbakeji Aare ti Isuna
Marcel ti je onisee gbogbogbo, ko to bere irin-ajo si isuna. Ko to bere Travelflex, o ti ni sise isakoso ti gbogbo abala isuna awon ile-ise elegbogi ka kiri agbaye, lati Netherland de Thailand de Italy. Lowolowo bayii, o nse isakoso Isanu ati isiro Travelflex.
Alex Putzolu
Olugbeejade Blockchain
Alex kawe ninu imo ero komputa ati IT o si ti je olupin ise komputa ti o n sise. O bere si nife si Bitcoin, blockchain ati ohun gbogbo to jemo cryptocurrency. Idojuko akoko re ni Idagbasoke blockchain.
Yosui Kitahara
Oludari Idagbasoke
Yosui kawe ninu isalaye fun tekinoloji ni ile-eko giga Murdoch ninu ilu Australia. O ni eri fun ohun gbogbo ti o jemo blockchain. O nse idanwo, ko, se atunse ati itoju awon eto wa ti o da lori blockchain.
Andy Acataldi
Iwadi ati Idagbasoke
Andy ni olori iwadi ati idagbasoke fun gbogbo abala cryptocurrency. Ise pataki re ni lati se iwadi gbogbo awon anfani ti o n yoju fun ile-ise lati se imugborosi. Ti yo si di anfani pupo fun awon onibara.
Steve Baker
Onisowo
Steve ni oloye leyin isowo owo Forex eleyi ti o bere ni ojo ori meedogun o si ni aseyori ti o po ninu ise re. Inagije re ni oloju square nitori afisodi re si oju komputa ti a si ma bi oja owo se lo. Steve n je, mu ati sun lori owo sise, oun lo fa agbara nla ti o ni ninu aladani o si ti fihan pe kosemani dukia lo je. Si ile-ise yii lati igba ti o ti darapo mo wa ni odun 2016.
Tineke Dekker
Onise Apeere
Tineke ni onise apeere wa. O ti rin irin-ajo ka kiri gbogbo aye o si ti wa pelu aimoye ise ikanse atinuda kakiri agbaye. O ti n ko ipa pataki ninu cryptocurrency lati. Odun 2014 o si je idunu re pe o wa pelu ise akanse yii; sise apapo atinuda, irin-ajo pelu Cryptocurrency
Pavel Capote
Ibanisoro
Bi o se le soju ede meta lo, Pavel lo wa ni isakoso awon European ati South American awon omo-ise PR Travelflex. Pavel ni o nse isakoso social media, pelu amojuto ati idari Ibanisoro ti abenu ati ita Travelflex.
Tukta Sangkham
Ibanisoro
Tukta ni o wa ni isakoso gbogbo ohun to je ati ibanisoro ni Asia. O ma wa pelu ero ibanisoro alagbeka re ni gbogbo igba, a si ma ye awon ikanni social media re wo lati mo Alaye titun lori cryptocurrencies.
Kittiya Prommao
Numba Awon Osisel’apapo Ni Ile-Ise
Kittiya pari eko lori oroinuokan ni ile iwe giga Chulalongkorn. O ni oju to monudoko lati ri agbara eniyan. Ni Travelflex, oun lo wa ni isakoso lati ma wa awon eniyan otun lati darapo mo egbe wa.
E sise pelu wa

Travelflex je ile-ie ti o n dagba si pelu awon alabasise ka kiri agbanla aye. A ni lo awon eyan ti o n fe ipenija to dara. To ba wu e lati ma sise pelu wa, o le fi awon alaye (iwuri ati CV re ni PDF abi doc) si

Ti a ba riwipe o le je dukia nla si egbe wa, a o yoo pada si odo re. lowolwo, a n wa awon wonyi:

FUN IBASORO
Alaye onibasoro
Fun gbogbo agbeyewo, awon ibeere osunwon ati awon ibeere miran, o le kan si wa lori email:
Wo ile
O yoo ṣe atunṣe ni kete
Jọwọ Tẹ Awọn alaye Rẹ sii
Aṣiṣe aimọ kan ṣẹlẹ
O ṣeun fun fiforukọṣilẹ!
O yoo ṣe atunṣe ni kete
OK
E dupe!
A yoo pada si ọ laipe.
OK
We have received a very large amount of orders and doing our best to process them as soon as possible. If you are still waiting for your coins to be credited please be advised that the process can take up to 3 weeks.
OK